Gospel SongsTope Alabi Songs

Opin Irin Ajo – Tope Alabi (Remix)

Download Opin Irin Ajo - Tope Alabi (Remix)

Opin Irin Ajo
Opin Irin Ajo – Mp3

Download Opin Irin Ajo (Medley) (Live) Gospel songs from anointed singer and artist Tope Alabi Download and be blessed. Tope Alabi’s popular worship song that widespread over the country and also gaining massive recognition online.

Opin Irin Ajo – Mp3

Download Mp3: Opin Irin Ajo

official lyrics: ♪ Opin Irin Ajo (Remix) ♪

Bi e ba n gbo t’omode n ge ‘gi ni ‘gbo
Agba lo le mo ‘bi to mi a wo si
B’omode ba rin irin ajo loju agba
O le ma ba agba mo ni’le to ba de o
Irin ajo eda laye, Olorun lo mo
Opin irin ajo k’a fi s’adura
Opin irin ajo temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o k’a jagunmolu

Bi e ba n gbo t’omode n ge ‘gi ni ‘gbo
Agba lo le mo ‘bi to mi a wo si
B’omode ba rin irin ajo loju agba
O le ma ba agba mo ni’le to ba de o
Irin ajo eda laye, Olorun lo mo
Opin irin ajo k’a fi s’adura
Opin irin ajo temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o k’a jagunmolu
Opin irin ajo o o laye
Abalo ababo wa ninu aye

READ :  Emimimo - TY Bello Ft Tope Alabi (Mp3, Lyrics, Videos)

Laisi laala ko ma si isinmi
Eni to maa yege o, a rin un wi
O fe lowo, o fe ko’le o ninu aye
Laisi ‘ranwo Olorun ofo lo ma ja si
Eni fe se rere o, dandan a w’oju Olorun
Esu o ni fun o lookan, ko ma fi gb’eedegbaa
Ona eburu lonitohun yen a fi parun
Opin irin ajo temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o, ka jagunmolu
Laala ninu aye, irin ajo aye
Ogun to n ja, t’Olorun nse won a re koja lo
Opin irin ajo ni’ku, a gbe ni ju langba si koto
Eni ti ku ni’sinmi, iyen p’orisirisi

Ibi ta o re, b’a d’orun lo ja ju o
Ibo lodo temi tire, ore je ka roo
Oba je ko san wa o, ka b’Olorun nile
Opin irin ajo temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o, ka jagunmolu
Jesu ti wa s’aye lati ku fun emi ati iwo, ore ma se ko ife
Jesu yi o
Nitori o san fun eniyan lati ma wa’ye rara, ju pe k’o pada
s’orun apaadi lo
Ore mi mo n be o, iku Jesu Kristi, mase je ko ja s’asan
Oniwakuwa ronu k’o lo ja’wo
Alagbere, oniwokuwo k’e ya so se
Ole, janduku, e ku ireti ojo idajo

READ :  Mercy Chinwo ft Olaitan Odoko - Rest (Lyrics, Mp3)

K’aborisa ko pa un ti o soro ti k’o sin lOhun
E ye bo satani lowo k’e tun f’enu ko Jesu
S’eke s’ajo ko s’eni t’o gb’alubosa e gbo, to maa fi ka ‘la
o, iyen d’eewo
temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o, ka jagunmolu
Aye o ni ‘boji, orun ni ‘boji aye
Eni da ‘mi siwaju lo n te ‘le tutu
Eni lo s’ajo to mi a de ti o ti ferese
Iyen gbe ‘se ile re f’onisona ko w’eyin wo rara
K’o to dele, iji ka’ja, ojo wole p’eru
Iboji a da ninu ile to ti d’aatan
Eni ye ko wole mu’mi sinmi a tun ko sise

READ :  Excess Love - Mercy Chinwo (Mp3, Lyrics and Video)

isinmi lo ye k’o je
Bi e ba n gbo t’omode n ge ‘gi ni ‘gbo
Agba lo le mo ‘bi to mi a wo si
B’omode ba rin irin ajo loju agba
O le ma ba agba mo ni’le to ba de o
Irin ajo eda laye, Olorun lo mo
k’a fi s’adura
Opin irin ajo temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o k’a jagunmolu
Bi e ba n gbo t’omode n ge ‘gi ni ‘gbo
Agba lo le mo ‘bi to mi a wo si

B’omode ba rin irin ajo loju agba
O le ma ba agba mo ni’le to ba de o
Irin ajo eda laye, Olorun lo mo
Opin irin ajo k’a fi s’adura
Opin irin ajo temi tire ninu aye
Oba je ko san wa o k’a jagunmolu

Tags

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button
Close
%d bloggers like this: