Gospel SongsTope Alabi Songs

Nigbati Mo Ro O – Tope Alabi

Download Nigbati Mo Ro O - Tope Alabi

Nigbati Mo Ro O - Tope Alabi
Tope Alabi.

Download Nigbati Mo Ro O Yoruba gospel song by Tope Alabi.

Lyrics (Chorus)
Igba ti mo ro ise iyanu re laaye mi
Mori pe o ga
Mori pe o ga pupo

Igba ti mo ro ise iyanu re laaye mi
Mori pe o ga
Mori pe o ga pupo

Lati inu oyun
Titi di omo owo o
Igba mo wa lomo owo
Awon ota gba wipe iku o pa mi

READ :  Tope Alabi Song Logan Ti Ode Ft. TY Bello & George Mp3
Download Nigbati Mo Ro O

Download Nigbati Mo Ro O – Mp3

Mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
Baba o sho mi, ore re yi o lakawe

Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi
Titi mo fi wa di agbalagba o

Igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi
Mo wa ri pe o oga o pupo

READ :  Wetin I Gain – Frank Edwards | Lyrics

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.

READ :  Download Je Ka Ki - Tope Alabi Mp3, Lyrics

Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.

Ogun ti eniyan ja n’agba, o poju Ogun ewe lo
Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi…

Source: Gospelhotspot

Tags

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button
Close
%d bloggers like this: